Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí Jósúà kò fa ọwọ́ ọ rẹ̀ tí ó di ọ̀kọ̀ mú sí ẹ̀yìn, títí ó fi pa gbogbo àwọn tí ń gbé ìlú Áì run.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:26 ni o tọ