Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jóṣúà àti gbogbo àwọn ará Ísírẹ́lì rí i pé àwọn tí ó ba ti gba ìlú náà, tí èéfín ìlú náà sì ń gòkè, wọ́n yí padà wọ́n sì kọlu àwọn ọkùnrin Áì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:21 ni o tọ