Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti ṣe èyí tán, àwọn ọkùnrin tí ó ba sì dìde kánkán kúrò ní ipò wọn, wọ́n sáré ṣíwájú. Wọn wọ ìlú náà, wọ́n gbà á, wọ́n sì yára ti iná bọ̀ ọ́.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:19 ni o tọ