Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì ku ọkùnrin kan ní Áì tàbi Bétélì tí kò tẹ̀lé Ísírẹ́lì. Wọ́n sì fi ìlẹ̀kùn ibodè náà sílẹ̀ ní ṣíṣí, wọ́n sì ń lépa àwọn ará Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:17 ni o tọ