Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kéjì Jóṣúà kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀, òun àti àwọn olórí Ísírẹ́lì, wọ́n wọ́de ogun lọ sí Áì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:10 ni o tọ