Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì kó òkítì òkúta ńlá lé Ákánì lórí títí di òní yìí. Nígbà náà ní Olúwa sì yí ìbínú gbígbóná rẹ̀ padà. Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ ibẹ̀ ní Àfonífojì Ákórì láti ìgbà náà

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:26 ni o tọ