Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà sì wí pé, “Èé ṣe tí ìwọ mú wàhálà yìí wá sí orí i wa? Olúwa yóò mú ìpọ́njú wá sí orí ìwọ náà lónìí.”Nígbà náà ni gbogbo Ísírẹ́lì sọ ọ́ ní òkúta pa, lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n sọ àwọn tó kù ní òkúta pa tán, wọ́n sì jó wọn níná.

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:25 ni o tọ