Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kéjì Àjọ-ìrékọjá, ní ọjọ́ náà gan-an ni, wọ́n jẹ nínú; àwọn irè oko ilẹ̀ náà: àkàrà aláìwú, àti ọkà yíyan.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:11 ni o tọ