Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹ́rìnlá (14) oṣù náà (oṣù kẹ́rin) (4) nígbà tí wọ́n pàgọ́ ní Gílígálì ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹ́ríkò, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe ọdún Àjọ-ìrékọjá.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:10 ni o tọ