Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹyin yóò lè mọ ọ̀nà tí ẹ ó gbà, torí pé ẹ̀yin kò gba ọ̀nà yìí tẹ́lẹ̀ rí. Ṣùgbọ́n àlàfo gbọdọ̀ wà ní àárin yín àti àpótí náà, tó bí ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún un mítà (1000).”

Ka pipe ipin Jóṣúà 3

Wo Jóṣúà 3:4 ni o tọ