Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì pàṣẹ fún àwọn ènìyàn pé: “Nígbà tí ẹ bá rí àpótí i májẹ̀mú Olúwa, Ọlọ́run yín, tí àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì rù ú, nígbà náà ni ẹ̀yin yóò sí kúrò ní ipò o yín, ẹ̀yin yóò sì máa tẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Jóṣúà 3

Wo Jóṣúà 3:3 ni o tọ