Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo mú àwọn baba yín jáde kúrò ní Éjíbítì, ẹ wá sí òkun, àwọn ará Éjíbítì lépa wọn pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin títí ó fi dé Òkun pupa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:6 ni o tọ