Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“E wò ó!” ó wí fún gbogbo ènìyàn pé, “Òkúta yìí ni yóò jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wa, nítorí ó ti gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ fún wa. Yóò jẹ́ ẹlẹ́rìí yín tí ẹ bá ṣe àìṣòtítọ́ sí Ọlọ́run yín.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:27 ni o tọ