Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni Jóṣúà wí pé, “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí ara yín pé, ẹ ti yàn láti sin Olúwa.”Wọ́n dáhùn wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àwa ni ẹlẹ́rìí.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:22 ni o tọ