Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsin yìí ẹ bẹ̀rù Olúwa, kí ẹ sì máa sìn ín ní òtítọ́ àti òdodo. Kí ẹ sì mú òrìṣà tí àwọn baba ńlá yín sìn ní ìkọjá odò àti ní Éjíbítì kúrò, kí ẹ sì máa sin Olúwa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:14 ni o tọ