Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹni tí ó bá sèèsì pa ènìyàn tàbí tí ó bá pa ènìyàn láìmọ̀ọ́mọ̀ lè sálọ sí ibẹ̀, fún ààbò lọ́wọ́ olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó pa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 20

Wo Jóṣúà 20:3 ni o tọ