Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nísinsìnyìí, ẹ jọ̀wọ́, ẹ búra fún mi ní ti Olúwa pé ẹ̀yin yóò ṣe àánú fún ìdílé mi, nítorí pé mo ti ṣe yín ní oore. Ẹ fún mi ní àmì tó dájú:

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:12 ni o tọ