Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 19:39-46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

39. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Náfitalì, ní agbo ilé sí agbo ilé.

40. Ìbò keje jáde fún ẹ̀yà Dánì, ní agbo ilé ní agbo ilé.

41. Ilẹ̀ ìní wọn nì wọ̀nyí:Sórà, Éṣtaólì, Írí-Ṣẹ́mẹ́sì,

42. Ṣáálábínì, Áíjálónì, Ítílà,

43. Élónì, Tímínà, Ékírónì,

44. Élítékè, Gíbétónì, Báálátì,

45. Jéúdì, Béné-Bérákì, Gátí-Rímónì,

46. Mé Jákónì àti Rákónì, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó kọjú sí Jópà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 19