Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 19:37-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Kédéṣì, Édíréì, Ẹ́ní-Hásórì,

38. Írónì, Mígídálì-Élì, Hórémù, Bẹ́tì-Ánátì àti Bẹ́tì-Sẹ́mẹ́ṣì. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mọ́kàndínlógún àti ìletò wọn.

39. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Náfitalì, ní agbo ilé sí agbo ilé.

40. Ìbò keje jáde fún ẹ̀yà Dánì, ní agbo ilé ní agbo ilé.

Ka pipe ipin Jóṣúà 19