Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà sì dé Tábórì, Ṣáhásúmà, àti Bẹti Ṣẹ́mẹ́ṣì, ó sì pin ní Jọ́dánì. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rindínlógún àti iletò wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 19

Wo Jóṣúà 19:22 ni o tọ