Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì lọ bá Élíásárì àlùfáà, Jóṣúà ọmọ Núnì, àti àwọn olórí wí pé, “Olúwa pàṣẹ fún Mósè láti fún wa ní ìní ní àárin àwọn arákùnrin wa.” Bẹ́ẹ̀ ni Jóṣúà fún wọn ní ìní pẹ̀lú àwọn arákùnrin baba wọn, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:4 ni o tọ