Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà gòkè lọ títí dé Débírì láti Àfonífojì Ákórì, ó sì yípadà sí àríwá Gílígálì, èyí tí ó dojú kọ iwájú Ádúmímù gúsù ti Gọ́ọ́jì. Ó sì tẹ̀síwájù sí apá omi Ẹbi Ṣéméṣì, ó sì jáde sí Ẹni Rógélì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 15

Wo Jóṣúà 15:7 ni o tọ