Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:58-63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

58. Hálíúlì, Bẹti-Súrì, Gédórì,

59. Máárátì, Bẹti-Ánótì àti Élítékónì: ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn.

60. Kiriati Báálì (tí í ṣe, Kiriati Jeárímù) àti Rábà ìlú méjì àti ìletò wọn.

61. Ní asálẹ̀:Bẹti-Árábà, Mídínì, Sékákà,

62. Níbíṣánì, Ìlú Iyọ̀ àti Ẹni-Gẹ́dì, ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn.

63. Júdà kò lè lé àwọn ọmọ Jébúsì jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jérúsálẹ́mù. Àwọn ará Jébúsì sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Júdà títí dí òní.

Ka pipe ipin Jóṣúà 15