Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:49-55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

49. Dánà, Kíríátì-Sánà (tí í se Débírì),

50. Ánábù, Ésítémò, Ánímù,

51. Gósénì, Hólónì àti Gílónì, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.

52. Árabù, Dúmà, ṣ Éṣánì,

53. Jánímù, Bẹti-Tápúà, Áfékà,

54. Húmútà, Kíríátì Áríbà (tí í se, Hébúrónì) àti Síori: ìlú mẹ́sàn án àti àwọn ìletò rẹ̀

55. Máónì, Kámẹ́lì, Sífì, Jútà,

Ka pipe ipin Jóṣúà 15