Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:48-53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

48. Ní ilẹ̀ òkè náà:Ṣámírì, Játírì, Sókò,

49. Dánà, Kíríátì-Sánà (tí í se Débírì),

50. Ánábù, Ésítémò, Ánímù,

51. Gósénì, Hólónì àti Gílónì, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.

52. Árabù, Dúmà, ṣ Éṣánì,

53. Jánímù, Bẹti-Tápúà, Áfékà,

Ka pipe ipin Jóṣúà 15