Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:46-51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

46. ìwọ̀-oòrùn Ékírónì, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòòsí Áṣídódù, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn,

47. Áṣídódù, agbégbé ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gásà, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé Wádì ti Éjíbítì àti agbégbé òkun ńlá (òkun Mẹditareníà).

48. Ní ilẹ̀ òkè náà:Ṣámírì, Játírì, Sókò,

49. Dánà, Kíríátì-Sánà (tí í se Débírì),

50. Ánábù, Ésítémò, Ánímù,

51. Gósénì, Hólónì àti Gílónì, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 15