Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:44-49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

44. Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)

45. Ékírónì, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká,

46. ìwọ̀-oòrùn Ékírónì, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòòsí Áṣídódù, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn,

47. Áṣídódù, agbégbé ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gásà, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé Wádì ti Éjíbítì àti agbégbé òkun ńlá (òkun Mẹditareníà).

48. Ní ilẹ̀ òkè náà:Ṣámírì, Játírì, Sókò,

49. Dánà, Kíríátì-Sánà (tí í se Débírì),

Ka pipe ipin Jóṣúà 15