Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:38-45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Díléánì, Mísípà, Jókítẹ́lì,

39. Lákísì, Bósíkátì, Égílónì,

40. Kábónì, Lámásì, Kítílísì,

41. Gédérótì, Bẹti-Dágónì, Náámà àti Mákédà, ìlú mẹ́rìndín ní ogún àti ìletò wọn.

42. Líbínà, Étíérì, Áṣánì,

43. Hífítà, Ásínà, Nésíbù,

44. Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)

45. Ékírónì, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká,

Ka pipe ipin Jóṣúà 15