Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:36-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

36. Ṣááráímù, Ádítaímù àti Gédérà (tàbí Gérérótíámù), ìlú mẹ́rìnlá àti àwọn ìletò wọn.

37. Sénánì, Hádáṣà, Mígídánì-Gádì,

38. Díléánì, Mísípà, Jókítẹ́lì,

39. Lákísì, Bósíkátì, Égílónì,

40. Kábónì, Lámásì, Kítílísì,

41. Gédérótì, Bẹti-Dágónì, Náámà àti Mákédà, ìlú mẹ́rìndín ní ogún àti ìletò wọn.

42. Líbínà, Étíérì, Áṣánì,

43. Hífítà, Ásínà, Nésíbù,

44. Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)

Ka pipe ipin Jóṣúà 15