Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:21-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ìlú ìpẹ̀kun gúsù ti ẹ̀yà Júdà ní Négéfi ní ààlà Édómù niwọ̀nyí:Kabísélì, Édérì, Jágúrì,

22. Kínà, Dímónà, Ádádà,

23. Kédéṣì, Hásórì, Ítina,

24. Sífì, Télémù, Bíálótì,

25. Hasori-Hádátà, Kerioti-Hésírónì (tí í ṣe Hásórì),

26. Ámámù, Sẹ́mà, Móládà,

27. Hasa-Gádà, Hésímónì, Bẹti-Pélétì,

28. Hasari-Ṣúálì, Bíáṣébà, Bísíótíyà,

Ka pipe ipin Jóṣúà 15