Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà tí ó yípo láti Báálà lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn sí okè Séírì, ó sì lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àríwá òkè Jéárímù (tí íṣe, Késálónì), ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí Bẹti-Sẹ́mẹ́sì, ó sì kọja lọ sí Tímínà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 15

Wo Jóṣúà 15:10 ni o tọ