Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìnyí fi ìlú orí òkè fún mi èyí tí Olúwa ṣe ìlérí fún mi ní ọjọ́ náà. Ìwọ gbọ́ ní ìgbà náà pé àwọn ọmọ Ánákì ti wà ní ibẹ̀, àti àwọn ìlú wọn tóbi, pé ó sì se olódi, ṣùgbọ́n bí Olúwa ba fẹ́, èmi yóò lé wọn jáde, gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:12 ni o tọ