Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọba Ámórì máràrùn, ọba Jérúsálẹ́mù, Hébúrónì, Jámútù, Lákíṣì àti Égílónì-kó ara wọn jọ, wọ́n sì gòkè, àwọn àti gbogbo ogun wọn, wọ́n sì dojú kọ Gíbíónì, wọ́n sì kọ lù ú.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:5 ni o tọ