Gbogbo àwọn ọba wọ̀nyí àti ilẹ̀ wọn ní Jósúà sẹ́gun ní ìwọ́de ogun ẹ́ẹ̀kan, nítorí tí Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, jà fún Ísírẹ́lì.