Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo agbégbé náà, ìlú òkè, Négéfi, ìlú ẹsẹ̀ òkè ti ìhà ìwọ̀-óòrùn àti gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè pẹ̀lú gbogbo ọba, wọn kò dá ẹnìkankan sí. Ó pa gbogbo ohun alààyè run pátapáta, gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ti pàṣẹ.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:40 ni o tọ