Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì fi Lákísì lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́, Jóṣúà sì gbà á ní ọjọ́ kéjì. Ìlú náà àti gbogbo ènìyàn ibẹ̀ ní ó fi idà pá gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí Líbínà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:32 ni o tọ