Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì wí pé, “Ẹ yí òkúta ńlá dí ẹnu ihò àpáta náà, kí ẹ sì yan àwọn ọkùnrin sí ibẹ̀ láti ṣọ́ ọ.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:18 ni o tọ