Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni òòrùn náà sì dúró jẹ́,òṣùpá náà sì dúró,títí tí ìlú náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀ta rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ nínú ìwé Jáṣárì.Oòrùn sì dúró ní agbede-méjì ọ̀run, kò sì wọ̀ ní ìwọ̀n odindi ọjọ́ kan.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:13 ni o tọ