Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa mú kí wọn dààmú níwájú àwọn Ísírẹ́lì, wọ́n sì pa wọ́n ní ìpakúpa ní Gíbíónì. Ísírẹ́lì sì lépa wọn ní ọ̀nà tí ó lọ sí Bẹti-Hórónì, ó sì pa wọ́n dé Ásékà, àti Mákédà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:10 ni o tọ