Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní báyìí tí Adoni-Sédékì ọba Jérúsálẹ́mù gbọ́ pé Jóṣúà ti gba Áì, tí ó sì ti pa wọ́n pátapáta; tí ó sì ṣe sí Áì àti ọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí Jẹ́ríkò àti ọba rẹ̀, àti bí àwọn ènìyàn Gíbíónì ti ṣe àdéhùn àlàáfíà pẹ̀lú Ísírẹ́lì, tí wọ́n sì ń gbé nítòsí wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:1 ni o tọ