Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe jẹ́ kí Ìwé Ofin yìí kúrò ní ẹnu ù rẹ, máa ṣe àṣàrò nínú u rẹ̀ ní ọ̀ṣán àti ní òru, kí ìwọ kí ó lè ṣọ́ra láti ṣe gbogbo nǹkan tí a kọ sí inú u rẹ̀. Nígbà náà ni yóò dára fún ọ, ìwọ yóò sì ní àṣeyọrí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 1

Wo Jóṣúà 1:8 ni o tọ