Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì yóò sí ẹnikẹ́ni tí yóò le è dúró níwájú ù rẹ ní ọjọ́ ayé è rẹ gbogbo. Bí mo ti wà pẹ̀lú u Mósè, bẹ́ẹ̀ ni Èmi yóò wà pẹ̀lú ù rẹ, Èmi kì yóò fi ọ́ sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni Èmi kì yóò kọ̀ ọ́.

Ka pipe ipin Jóṣúà 1

Wo Jóṣúà 1:5 ni o tọ