Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 7:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Sé ìjà kò ha si fún ènìyàn lórí ilẹ̀?Ọjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú kò ha dàbí ọjọ́ alágbàṣe?

2. Bí ọmọ-ọ̀dọ̀ tí máa ń kanjú bojúwo òjíjìàti bí alágbàṣe ti í kánjú wo ọ̀nà owó iṣẹ́ rẹ̀.

3. Bẹ́ẹ̀ ni a mú mi ní ìbànújẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù,òru ìdáni-lágara ni a sì là sílẹ̀ fún mi.

Ka pipe ipin Jóòbù 7