Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti mo dùbúlẹ̀, ‘Èmi wí pé nígbà wo ni èmi ó dìde?’Tí òru yóò sì kọjá? Ó sì tó fún mi láti yí síhìn-ín yí sọ́hùn-únTítí yóò fi di ògúlùtu erùpẹ̀ ti a fi wọ̀ mí ní aṣọ,àwọ̀ mi bù, ó sì di sísun ni.

Ka pipe ipin Jóòbù 7

Wo Jóòbù 7:4 ni o tọ