Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 38:38-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Nígbà tí erupẹ̀ di líle, àtiògúlùtú dípò?

39. “Ìwọ ha dẹ ọdẹ fún abo kìnnìún bí?Ìwọ ó sì tẹ ebi ẹgbọ̀rọ̀ kìnnìún lọ́rùn,

40. Nígbà tí wọ́n bá ń mọ́lẹ̀ nínú ihòtí wọ́n sì ba ní ibùba de ohun ọdẹ?

Ka pipe ipin Jóòbù 38