Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 38:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Di ẹ̀gbẹ́ ara rẹ ní àmùrè bíọkùnrin nísinsin yìí, nítorí péèmi yóò béèrè lọ́wọ́ rẹ kí o sì dámi lóhùn.

4. “Níbo ni ìwọ wà nígbà ti mo fiìpìnlẹ̀ ayé sọlẹ̀? Wí bí ìwọ bá mòye.

5. Ta ni ó fi ìwọ̀ rẹ lélẹ̀, dájú bí ìwọbá mọ̀ ọ́n? Tàbí ta ni ó ta okùn wíwọ̀n sórí rẹ?

Ka pipe ipin Jóòbù 38