Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 38:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Olúwa dá Jóòbù lóhùn láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé:

2. “Ta ni èyí tí ń fi ọ̀rọ̀ àìní ìgbirò ṣuìmọ̀ ní òkùnkùn?

3. Di ẹ̀gbẹ́ ara rẹ ní àmùrè bíọkùnrin nísinsin yìí, nítorí péèmi yóò béèrè lọ́wọ́ rẹ kí o sì dámi lóhùn.

Ka pipe ipin Jóòbù 38