Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 36:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Nitorí pé nípa wọn ní ń ṣe dájọ́àwọn orílè èdè ènìyàn; ó sí ń pèsè oúnjẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.

32. Ó fi ìmọ́lẹ̀ bo ọwọ́ rẹ̀ méjèèje ó sìrán sí ẹni olódì.

33. Ariwo àrá rẹ̀ fi ìjì hàn ní; ọ̀wọ́ẹran pẹ̀lú wí pé, ó súnmọ́ etílé!

Ka pipe ipin Jóòbù 36