Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 27:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Pẹ̀lúpẹ̀lú Jóòbù sì tún sọ kún ọ̀rọ̀ òwe rẹ̀, ó sì wí pé:

2. “Bí Ọlọ́run ti ń bẹ, ẹni tí ógba ìdájọ́ mi lọ, àti Olódùmárè tí ó bà mi ní ọkàn jẹ́;

Ka pipe ipin Jóòbù 27