Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 26:13-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Nípa ẹ̀mí rẹ̀ ni ó ti ṣe ọ̀run níọ̀sọ́; ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti dá ejò wíwo nì.

14. Kíyèsí i, èyí ní òpin ọ̀nà rẹ̀;ohùn èyí tí a gbọ́ ti kéré tó!Ta ni ẹni náà tí òye àrá agbára rẹ̀ lè yé?”

Ka pipe ipin Jóòbù 26